20/05/2022
IBERU OLORUN A MAA MU ARISIKI WA A SI MAA MU ADANWO LO.
Ojise Olohun SAW so pe Eniti o ba dun mo Ninu wipe ki oun naa je eni aponle pupo Lodo Olohun, ki o Maa paya Olohun, Olohun ti ola re ga ti so wipe_Eniti o ba nberu olorun, olorun yio SE ibuyojade kuro Ninu isoro fun, yio si se ARISIKI fun un. Jumat Mufeedat